Ọ̀pá tírín kanlẹ̀ ó kan ọ̀run. Kíni o?
A ti wá bọ́ sí ìgbà òjò wàyí o. Ojoojúmọ́ ni òjò ń rọ̀ báyìí. Ẹni tí kò bá wọ'ṣọ òjò, òtútù ni olúwarẹ̀ ń fi ṣeré.
Àmọ́ ó kúkú ti mọ́n wọn lára ní ilẹ̀ yí. Òjò ò ṣẹ̀ṣẹ̀ máa rọ̀ báyìí. Àbáláyé ni. Olúkálukú ti mú àbùadà rẹ̀ lọ́wọ́ lọ ibiṣẹ́. Gbàrà tí òjò ba bẹ̀rẹ̀ ni olúkálukú ń nà án sókè borí.
Ìbùkún ni òjò jẹ́ o jàre. Máa rọ̀ lọ́.

Comments
Post a Comment