Àwọn ọkọ̀ àti kẹ̀kẹ́ akérò ní Ìlú Èkó

Nkankan tó wùmí ní ìlú Èkó ni bí wọ́n ṣe kun gbogbo ọkọ̀ àti kẹ̀kẹ́ akérò ní ọ̀dà kannáà.  Èyí máà nmú kí gbogbo wọn bárawọn mu dáadáa kí wọ́n sì gúnrégé lójú, bíótilẹ̀jẹ́pé púpọ̀jù nínú wọn ti fẹ́ẹ̀ẹ́ bàjẹ́ tán.  Ó dàbí bí wọ́n ṣe kùn wọ́n náà ní ìlú New York ni.  Kì báà jẹ́ pé àwọn ọkọ̀ tiwọn tuntun nini yàtọ̀ sí tiwa :)

Comments

Popular posts from this blog

Kíni ìtumọ̀ "SIM Card" l’édè Yorùbá?

Etí òkun ìgbafẹ́

Mojúbà o!