Àkàrà

Oúnjẹ àárọ̀ àti ìpanu àtàtà ní ilẹ Yorùbá.  Òun náà ni wọ́n ń pè ní Acarajé ní Brasil.
Mo gbìyànjú ẹ̀ fúnra mi.  Kò dùn tó èyí tí ìyá mi máa ń dín, àmọ́ kò burú jù náà.  N kò rí ẹ̀kọ-mímu lọ́jọ́ náà.  Gbẹrẹfụ ni mo jẹ ẹ́ :)

Comments

Popular posts from this blog

Kíni ìtumọ̀ "SIM Card" l’édè Yorùbá?

Etí òkun ìgbafẹ́

Mojúbà o!