Àwọn ẹ̀yà ẹja onírúirú

Àwọn ẹ̀yà ẹja onírúirú ní wọ́n ń gbé'nú omi.  Mo lọ sí London Aquarium níjọ́sí, ibi tí wọ́n ti ṣe àkójọpọ̀ àwọn ẹja aláràbarà.  Díẹ̀ nínú àwọn tó jọmí lójú nìwọnyí.

Comments